top of page

NOTE: Bi o ba di alabukun fun ninu awon eto wonyi mase alaifi oro ranse nipa kiko oro si abala Comments eyiti o wa ni isale patapata tabi ti o ba ni alaaye tabi ibeere, o le ko sibe. Bakannaa o je abala aye lati ki ara wa lakoko yi ki a si ma saalaye bi nkan se nlo lagbegbe wa. (Comments)

For your offering:

Adewumi Nuru Joshua

ECO Bank:3511312706

FIRST DAY AND FIRST FRIDAY OF THE MONTH

 

Eks 14:4, Isa 42:8

 

1. Oluwa losu yi e tu mi sile ninu igbekun awon agba bi e se tu Israeli silek ki sehun tegbe nse.

 

2. Loruko Jesu, Oluwa losu yi jeki ororo orire, ibukun ati aseyori da le mi lori bi e se da le Josefu lori.

 

3. Oluwa ran oluranlowo atoke wa si mi losu yi bi e se ran si peteru.

 

4. Psa 23:5 - Ayo ati idunnu ti nmu ibanuje de ba awon ota, Oluwa se fun mi bi e se se fun Dafidi.

 

5. Oluwa, bi e se gbogo lori Farao ati Egipti, e gbogo lori gbogbo awon ti o ndena mi nigbati nba fe serere.

 

6. Oluwa jeki nyin o lori awon ota mi losu yi, bi Israeli se yin o lori Farao ati Egipti.

 

7. Ni ona ti nko le so ati ni awon ibiti nko mo, awon ohun ti yoo mu mi tesiwaju, e se fun mi losu yi.

 

8. Eyin ilekun ibukun to ti niwaju mi nitori covid 19, Oluwa fi ipa ati agbara re si.

 

9. Oluwa segun awon ti npe eleda mi ati oruko mi wa jeun loganjo oru.

 

10. Matt 3:9 Iwo to le si inu okuta jowo silekun ile omo mi, ki emi na kuro nipo iyagan.

 

(b) Iwo to le si inu okuta jowo si owo mi fun ibukun, ki nkuro ni ipo osi.

 

(c) Iwo ti o le si ini okuta jowo ona fun iseda mi, ki emi de ibi ilepa mi.

 

11. Oluwa gbogo lori awon agbara to nye ileri mo mi lowo lososu, gbogo lori agbara to nsun ojo ayo ati idunnu mi siwaju.

 

12. Oluwa ise ti e fi ran orun ati aye lati se lori aye mi, loruko Jesu, e se yori losu yi.

 

(b) Ohun ti e bere laye mi lati ibeere odun maase dawo re duro ayafi ti e ba yori re, ti emi na di olope.

 

13. Oluwa gbogo lori oro aye mi losu yi, ki nye fipa se ohun gbogbo ti nba nse.

 

14. Oluwa so ise iyanu re di pupo ninu aye mi, ki o si ran alaanu tie mi gan ko lero simi.

 

15. Joh 8:36 -Oluwa gbogo lori ijoba okunkun to fowosopo lori aye mi, kin le gba ominira to seleri fun mi

 

16. Oluwa fopin si iya ojukoroju ati tinu emi to nje bi e se fopin si ninu aye Hannah ati Jabesi.

 

17. Oluwa jeki adura mi ati ebe mu ki orun dahun soro aye mi, ki oorun mi to ti wo beresi nyo pada.

 

18. Qur 16:102 – Emi mimo, e ranmi lowo losu yi ki gbogbo adawole mi le yori si rere.

 

19. Owe 10:28 – Oluwa gbogbo ireti mi losu yi ayo ni ko jeko jasi.

 

20. Ireti awon eniyan buburu lori aye mi, ebi mi ati ise mi asan ni ko jeko jasi Olorun.

Beresi nbere ohun ti o fe fun osu yi.

NOTE: Mase gbagbe lati fi adura ran ihinrere yi lowo

 

Lehinna, o le fi ore re ranse si Account Nomba Ihinrere yi

Oluwa yoo bukun fun o, yoo si so o di pupo loruko Jesu Kristi amin

bottom of page