top of page
plogo.jpg

NOTE: O je pataki lati ka awon ese oro Olorun ti o wa ninu adura ti osu lati le ran wa lowo itumo adura ti a fe gba.

 

ORIN OPE.................30mins

ADURA OPE........... 10mins

 

O.D 92:1 - 2

1. Ki olukuluku ko orin ope meta lati fi dupe lowo Olorun, Oba to mu wa ri ipari osu keje layo ati alaafia.

2. Gbogbo wa yoo tun dupe lowo Olohun fun aanu re lori gbogbo wa, fun Olorun to salaabo lori omode ati agba wa.

3. Jowo dupe lowo Olorun lori re ati lori ebi re fun oore re nigbagbogbo.

4. E jeki a dupe lowo Olorun lori ipade tan imole osu to koja, ki a si tun dupe fun ohun ti Olorun yoo se ni ipade tan imole ti oni.

5. Oluwa mo dupe fun imole oore ofe ti e o tan sinu aye mi loni

 

ADURA IDARIJI ESE ATI AANU...... 10mins

 

Matt 13:41

1. Oluwa fi aanu ati eje re pa ese mi re.

 

2. Oba ti nje Astagafudullahi jowo faanu gbami, ma jeki ese dena adura.

 

3. Oluwa ni gbogbo ona ti ese ti ndena adura  mi, Oluwa fannu gbami loru oni.

4. Oluwa saanu fun mi.

 

ADURA AGBARA EMI MIMO...... 10mins

 

             JOh 12:8

1. Emi imole Oluwa gbe wo mi.

 

2. Agbara imole Oluwa gbe wo mi.

3. Ina imole Oluwa gbe wo mi.

 

4. Ifororoyan imole Oluwa gbe wo mi.

 

5. Ohun ija imole ti maa fi segun Oluwa gbe wo mi.

6. Oluwa fun mi ni ase imole lati maa segun.

OPENING PRAYERS

(12:00am - 1:00am) 1 hour

Theme: Road  to Grace

You are all invited to

Theme: GRACIOUS GOD

2020 convention

Grace Ahead 

bottom of page