You are all invited to
2020 convention
Theme: GRACIOUS GOD
Grace Ahead
Theme: Road to Grace
Let there be light prayers
(1:00am - 3:00am) 2hrs
For your:
OFFERING
Adewumi Nuru Joshua
ECO Bank:3511312706
NOTE: O je pataki lati ka awon ese oro Olorun ti o wa ninu adura osu lati le ran wa lowo itumo adura ti a fe gba.
Lesson: Rom: 10 - 16.
Gen1:1 – 3, Qur 6:63 - 64
1. Inu okunkun ti ota korajo po si ponmiloju, Oluwa fimole tu won ka
2. Tu asiri awon eni okunkun to joko sikoko fogun ja aye mi ati ise mi
3. Tan mole si gbogbo ogun farapamo sikoko ja aye mi, ki o si fi imole segun won.
4. Oluwa fi agbara re gbami lowo ogun alunibole togotogo
O.D 118:10 - 13
5. Oluwa fi oore ofe re gbami lowo ogun delay ati ifasehin ti aye fi nfogun ja mi
6. Ibi ikoko aye ti ota demi mole si togotogo Oluwa fina kolu ibe, ko si tumi sile togotogo
7. Enikeni to joko sikoko ponmi loju tabi gba eto mi, Oluwa fina kolu, ki o si gbami lagbatan
8. Ibi ikoko to nbe ninu agbo ile baba ati iya mi, ti ota ati ogun idile joko si fogun jami Oluwa fina kolu ibe
9. Oluwa pa gbogbo ami to nbe lara mi ti won fi nmonitor mi ti ko jeki iyanu sele laye mi re.
10. Oluwa bami dana sun television taye fi si mi lara ti won fi ngba iyanu mi sonu
11. Oluwa bami fi ida pa aja ati emi ti aye fi nmonitor mi kiri loruko Jesu.
12. Oluwa bami segun ota to nmonitor mi losan ati loru
O.D 119:126
13. Awon eni ika to ba nibuba fogun jami, ko mi leru, Oluwa fina kolu won ko si ko eru mi fun mi
14. Oluwa o takoko gbami lowo awon to nfi iponju ati osi bami ja
15. Oluwa o takoko fi oore ofe nla gbami lowo ajaga koni tegbe ati ajaga waye lasan
16.Oluwa o to akoko ba ise awon ika eniyan se nikoko lori emi ati ayanmo je
17. Oluwa o to akoko lowo ogun ti o je nse ohun tegbe mi nse ki o si mu mi wo inu oore ofe nla
18. Oluwa fi oore ofe re gbami lowo ogun iku ojiji to nrin kiri niyoku odun yi.
18b. Oluwa mo ti sa si abe oore ofe re tebitebi mase jeki iku ojiji ko yanu ebi mi
Isa 45:3
19. Oluwa fi oore ofe re gbami jade nikoko taye gbe mi pamo si togotogo
O.D 118:14 - 17
20. Omo Oba ni mi, nipa oore ofe re, ma je ngbe igbe aye eru mo
21. Oluwa ma jeki nfara sinu ku, nipa oore ofe re fi ire aye mi wa mi ri
22. Oluwa fi imole oore ofe re yonda ibukun ati eto mi fun mi
23. Oluwa jeki irohin aluyo mi ko de loni, jeki iyipada otun ko de ba aye mi
24. Oluwa nipa oore ofe re jeki awon ireti ati adura mi beresi njasi eri ati ayo latoni lo
25. Nitori omo oore ofe ni mi latoni lo iyanu ko beresi nsele laye mi.
26. Oluwa fi imole re le gbogbo ohun to nsapere okunkun ninu aye mi
27. Oluwa tan imole sinu aye mi ki oloore ti o ran si mi le ri mi
Lehin naa bere si nbere ohun to fe
Na ore re soke ki o si fi bere ohun to fe, lehinna fi pamo di akoko ti a o se isin.
Tabi bere ohun to fe ki o si transfer ore re si account ile ijosin.