First day and First Friday Prayer
DATE: 01:05:2020
TIME: 5:30am - 7am
ADURA AABO
Psa 121:1 - 8.
1. Oluwa mo fi abo ati iso ebi mi le o lowo losu yi, pami mo tebitebi
2. Ofa ibon, ofa aye gbogbo ti aye ta simi, e pada lo ba awon to ta.
3. Okun iku ojiji ti aye ju si mi, jeki o pada mu awon to ju uu.
4. Eks 14:28 -29 – Oluwa see ki nyin o losu yi, ki gbogbo awon to fe pami ma kerora ninu iboju.
5. Oluwa ran Angeli re lati gba mi lowo awon ajuni sinu kanga iku.
6. Oluwa gbogo lori gbogbo awon to fe ju emi ati ebi mi sinu kanga ati ofin iku ojiji.
7. Oluwa jeki nyin o lori awon to ti pinnu lati ju mi sinu kanga iku.
8. Deut 30:19 – Nje loruko Jesu losu yi, mo yan iye tebitebi mi, mo ko iku ojiji, mo yan abo mo ko ibi gbogbo.