SUNDAY SCHOOL
Ka akosori, ka ibi kika, ka akori, ka oro akoso, ka ipa eko.
1. Ohun ti abala kini da le lori ni awon onigbagbo ti ngba iyanu lodo babalawo, olorisa, tabi darapo mo egbe okunkun fun ise iyanu lehinna ti won a wa si ile Olorun lati wa fi ise iyanu na yin Jesu logo pe oun loose. Awon to gba iyanu lodo Olorun nikan o ba enu ilekun wole.
2.Abala keji nso fun wa pe, ko fi se bi a se nso pe omo Olorun ni wa pe Jesu da awon aguntan tire mo.
3. Abala keta nso fun wa pe laisi aniani awon aguntan da oluso won mo. Be gege lo tun nsoro nipa igboran ni a fi le da awon aguntan mo nitori aguntan je eranko ti o ngboran ti o si tun ni emi irele.
4. Ipari eko yi nso fun wa nipa awon ohun ti a fi nbo ara wa gegebi aguntan nigbati ko ri be.
5. E jeki a dahun ibere Sunday school si abala comments.
TESIWAJU: