top of page
Worship and Praise………30 mins
Opening prayer..…………5 mins
Announcement: E jeki a so fun awon elegbe wa ti ko mo pe isin nlo lori website lati lo darapo mo.
Adura: (Gen 1:11) Iwo lo da ewe ati egbo.
1. Gbogbo ise ti won fi ewe ategbo se ni buburu lori aye mi, loruko Jesu Kristi ma baje.
2. Agbara ewe ategbo lori aye mi, Oluwa soo di asan.
3. Ogun to tipase ewe ategbo nja aye mi, o ya ma jona.
4. Owo to ga ju owo lo, fa mi jade ninu ihamo aye lo sinu ogo mi.
5. Owo Olorun o, wo inu aye mi seyanu.
TESIWAJU:
For your
1. Thithe :Access Bank
0093365322
2. Offering &
3. MonthlyOffering:
Adewumi Nuru Joshua
ECO Bank:3511312706
bottom of page